ASA,ERO All EDE NINU ISE-ONA• ♦ • ALAWOMO ■ UTIRESO• • • AKfNWUMI ISblA • • mDURO ADELEKE . V V Olootu ASA, ERO ATI EDE NINU ISE-ONA ALAWOMd-LlriRESO AKlNWUMI ISOLA• • © Olootu Duro A de!eke 2016 Enikem kd gbodo da ohunkdhun ko lati inu iwe yii ni pnakona yato fun ih ara tire laigba ase lowo dhkowe tabi ileese aseweta DB Martoy Books t 6 ti to labe ofin to de iwe gbigbe jade ISBN: 978-978-50689-9-3 A te iwe yii jade lati ileese DB Martoy Books Plots 5 & 7, Block C Alhaji Akinleye Layout Papa Zone Ogungbade, Ibadan, Nigeria. Tel: 08023133705 Typesetting by: Temisayo Ventures, U.I. Printed by: Agoro Publicity Company Ibadan DB MARTOY BOOKS, IBADAN 2016 iv Oro I$aaju Akinwumi Isola je pkan ninu awon agba ohkpwe Yoruba ti pwo ja ise-ona alatinuda re kan ewi, itan aroso, ere-onitan, teemp fiimu agbelewd. Gege bi ojinmi onise-ona ohun enu, o tun sagbekale awada ni oniran-h-ran ninu ise re ti d pe ni Fabu. 6 tun hande ninu awon ise ona re pe nise ni Isola maa h tele orisiirisii asa ati ise abinibi Yoruba jo sinu iwe re. A wa hun awon asa ati ise wonyi mo ise-ona alawbmp-litiresp re ni ona ti eegun fi wonu eegun. Ko wa je nhkan iyanu pe orisiirisii ise ni awon eniydn ti tari si ita yala ni ede Geesi tabi ede Yoruba. Sugbpn a kd ti i ni ise sandi ni ede Yoruba Iori ise Isola aya fi eyi ti won gbe jade ni ede Geesi ni ilu Amerika. Ise ti ogoorb awon onimo lowp si yii je ki a moriri ise-ona alawomo- litireso Isola. 6 han gbangba gbahgba pe pro erd imp ijinle imp Yoruba je Isola logon ninu ise-ona re. 6 tun safihan awon asa abinibi ti won je nhkan amuye ati amuyangan. Awon ompran tun pe akiyesi si pro awon obinrin ninu ise "Olddtp-kunrin" bee ni won tun tpka si iha ti o kp si awon elewu etu ti h daamu alakiisa laaarin ilu. Awon pmpran wonyi se itupale ispwolo-ede ninu ise Isola. Ninu akitiyan won ni a ti mo pe agbofee ede ni Akinwumi i se. Ede si je nhkan gboogi ti Isola fi sesp si awon ise pwp re. Ki n ma da a yin lagara, nhkan iyi ati eye ni pe won diidi gbe iwe jade ni ede Yoruba Iori gbajump agba dhkowe, ohkptan, opitan, asotan, gbede-gbeyo ti o ti buyi kun lilo, sisp ati kikp ede Yoruba kaakiri agbaye. Ise ki sinu iwe yii o jare! Ojogbon Gbbyega Alaba. v IJUBA ATI IDUPE A dupe Ipwo gbogbo awon ileese aseweta ti awon ohkpwe gbogbo se amuld iwe won Iona kan tabi dmiran ninu ise akada ti a fi osunsun re sun ise-ona alawdmp- litireso ti Akinwumi Orojide-isola. Lilo awon iwe yin ninu ise yii h tubo h pokiki ise yin niton pe awon iwe ti e gbe jade poju- owo de ibi pe won se e Id fun amuye ise awon omoran kppkah lati fi idi ootp mule. A tun dupe Ipwo gbogbo awon ti d dawpjppp ko ise akada yii. E ku ife ti e ni si Akinwumi Isola o. A si tun dupe lowo awon ti won nifee ati lowo si kiko apilekp fun Akinwumi Isola ti won kd ri ahfaani ati se bee. Ko tan sibe o, ahfaani si wa lojo iwaju. Mo dupe lowo awon eniyan wonyi; Omowe Adeyemi Adeyinka, Omowe Oluremi Olutunde, Ompwe Ahmed Adesanya, Ogbeni Adefemi Akinselpyin, Ogbeni Olumide Adegbddu ati Omidan Tolulope ibikunle fun akitiyan nipa sise akatunka ati atunse ninu ise yii. Edumare yoo bukun enikookan won, won yoo si moke lagbara Eledumare. 6 ye ki a yan an pe gbogbo ero ti d hande ninu ise yii je ti enikookan ti o ko ise naa. A dupe lowo gbogbo eni ti yoo ka a pelu. Ire o! 11 Duro Adeleke. vi akoOnu Oju iwe On Kin-in-ni: Akinwumi Isola 1 On Kejt: Obinrin Ati Imo-ijinle-Ero Yoruba Ninu Koseegbe 5 On Keta: Imeto Lawujo Yoruba bi 6 ti han ninu Ogun De Bode 18 On Kerin: Ero Ojogbon Isola Akewi Nipa Ipapoda Awon Akikanju Okunrin Meta Otooto 31 On Karun-un: Akinwumi IsOla: Akin Ohkowe ati Awon Aseweta Re 47 Ori Kefa: Isinnije ninu ise ona Litireso Akinwumi Ordjide - Isola 66 Ori Keje: Akinwumi Isola: Opitan Asotan 85 On Kejo: Ayinike Iseda Qrp Orukp Akinwumi Isola Ninu Fabu 92 On Kesan-an: Iha ti Akinwumi Isola kp si Esin ninu ere-onitan Abe Aabd Ni ilana Tipri Asatako-Im unisin 102 On Kewaa: Akinwumi Isola Gege Bi Olukoni Ni Asa 115 On Kpkanla: Akinwumi Isola Aderininposonu: Agbeyewd Awada Ajemp-Orp-ife Ninu Fabu 138 Ori Kejila: Agbeyewd Iio Ewi Alohun Yoruba Ninu Efunsetan Aniwura ti Akinwumi Isol a Kp 153 Ori Ketala: Ohkpwe, iwe Kiko ati Ero Ajemp-lilo: itupale lameyitp Lori Awon Ere-Onise Akinwumi Isola 162 Ori Kerinla: Akinwumi Isola gege bi Asetofabo: Apeere Afaimo Ati Awon Arbfo Miiran 173 vii On Keeedogun: ilo-Ede Ninu iwe Itan Arosp 'OLeKu' 187 On Kerindinlogun: Imojuwaye Oluko ati Ise Oluko Ninu 6 LeKuaXs Ogun Omode 205 On Kejidinlogun: Ete Isatakq Imunisin Ninu Ere-Onitan Yoruba: Akinwumi Isola Ati Adebayo Faleti Gege Bi Apeere 216 On Kejidinlogun: Akinwumi Isola Akewi 229 On Kpkandinlogun: Awon Orin Fiimu Saworoide Agogo Eewo Gege Bi Awojiji isele lie Wa 242 Ori Ogun: Ifamiparoko Ninu Fiimu Saworak/eati Agogo Eewo 260 Ori Kokanlelogun: Ikplura ati Itaporogan Ninu Awon Asayan Fiimu Akinwumi Isola 270 Ori Kejilelogun: Agbeyewb Awon Akpnibinrin Olu-Eda-Itan Ajemptan-Gidi Ninu Ere-Onitan Akinwumi Isola 281 Ori Ketalefogun: Iio Litireso Alohun Ninu Ogun Omode 295 Ori Kerinlelogun: Akinwumi Isola: Larija Isamulb idanilokanrb fun Akple Oruko Iwe Itan Arose 6 Le Ku 307 Ori Keeedpgbon: Batani igbekale Ati ipede Awada Ninu iwe Akinwumi Isola - Fabu 317 Ori Kerindinlpgbpn : Oju ti Akinwumi Isola fi wo isele awujp Yoruba ninu "Afaimo Ati Awon Ardfo Miirarf 338 Orf Ketadinlpgbon: Isatunse iwa Efunsetan Aniwura Ninu Fiimu Akinwumi Isola 351 viii 1 On Kej id in log bon: Adape: Okan Lara Opo to gbe Ise Ona Akinwumi Isola ro 366 On Kokandinlogbon: Isola Afigege Dara! iyiri Ifprodara Inu "Atatamo Atatamo I" Ninu Afaimo AtiAwon Ardfo Mi/ran 379 Ori Ogbon: Ifedeweda Ninu Koseegbe 389 Ori Kokanlelogbon: Iio Orin ninu Awon Fiimu Agbelewb Akinwumi Isola 402 Ori Kejilelogbon: Akinwumi Isola: Alore Asa ibile Yoruba Ninu Iwe Itan Ogun Ornate 411 Ori Ketalelogbon: Iio Orin Ninu Awon Iwe Atinuda Akinwumi Isola 423 Ori Kerinlelogbon: Afojusun Akinwumi Isola Gege Bi Orikowe Itan Aroso 432 On Karundinlogoji: ifedasefe ninu asayan orin inu fiimu Campus Queen 448 Ori Kerindinlogoji: Ara ti Akinwumi Isola fi kobdu ati Oro-ayalo da ninu 6 Ie ku 459 Ori Ketadinldgoji: Isafihan ipa obi ati iwa odo ninu fiimu 6 Le Ku 469 Ori Kejtdinlogdji: Lilo Orin lati gbe koko-oro jade ninu iwe Ere-Onitan Efunroye Tinubuti Akinwumi Isola ko 486 Ori Kokandinlogoji: Iha ti Akinwumi Isola ko si Egbe Ajajagbara to ri ja fun Eto ati Eto ilu ninu iwe Aye Ye Won Tan 498 Ori Ogoji: Isola pe Aadorin Odun 507 Oruko Awon Orikowe Akopa 509 ix Ori Keeedogun Iio-Ede Ninu Iwe Itaq Aroso'0 Le Ku Tibia yp Ojo Ifaara Opolopo awon onimb ede Yoruba Id ti sise Ion ede ati lid ede Yoruba* (Bamgbdse, 1974; Isola, 1978; Ola'tu'nji, 1984; Opa'dotun 2003; Ogunsina, 2009). Ede ni igi leyin ogba ise-ona kan. Ede ni 'iplle ise-ona. 8i ede ohkowe tabi anise-pna kan ba mehe, ise naa kd ni wuyi, kd ni je akagbadun. Ede je ona ati irin-ise 'iba'nisbro. Ede ni bpdmulerd ati emi litiresodfde ni o je epo ti i gbe oko litireso fin; dun si ni eje ti i fun litireso ni okun ati agba'ra lati mi..,Ede je ona 'ibanisoro ati ona lati gbe ero gkan ati Imblara eriiyan jade. Oun ni irin-ise ti awon ohkowe maa ri Id lati gbe ise ona alatinuda won kale. Olabimtan (1986: 77) se afomp arifani rila ti awon bhkowe/akewi ni ti eni ti Ki i se brikowe/akewi kd ni. 0 salaye pe: Arifani naa ni agba'ra lati Io ede ni ona ti d ba wu won, ki ew'i won ba Ie se ise ti won fe ki d se. Nipa bayii, kd si ete ti won kd le fi ede pa.(o.i 77) 0 salaye' siwa'ju si i pe: Akewi ki' i se eru ede, ohun amulb ni ede fun un. Oju tiwa ni d ti yapa, ni odd tire, d Io gbdldhun bhu'n ni ona ti o' Ie gbe ero inu jade ni. Fa'jenyb (2000: 39) nigba ti o ri fi 'ise pataki ede lawujo Yoruba han wa, jefii si i pe, pataki ni ede je lawujo eriiyan. Kd si se e fpwp rp seyin. Ewe, Yoruba jelran to mp ewbn ede, won mp ote ati oie ede pelu. Won ki i deede sorb sa'ka'la bi pbe ate. Pelu ogbp’n inu ati bye ikun ni won fi ma'a ri Io ede won. Siwa'ju si i, ede je ohun ti a fi ri ronu, ti a si fi ri fi ero inu wa han fun eldmiran, ya'la, nipa siso o jade lenu tabi kiko d sile (Adeyinka 2000: 138). Adebpwale (1998: 114), salaye pe ede ni bpakutele fun litireso niton lais'i tagiifi, awo kd le e hu'. O fi han s'iwaju pe ede se patak'i fun agbekale litireso, nitori pe ede ti ohkowe Id ni yob je k'i arokb fi b ri fi ise- ona re ran si awujo ye awon bhkawe re. Ede je irin-ise patak'i Ipwp dhkowe, nitori pe aimo-ede-e-lb le so gbogbo 'iyanju ohkowe di bfo, 6 di 187 Ie mu ki gbogbo faalaa re forisanpon, riitori Idi eyi, dhkpwe gbodp ni ikobiarasi ti 6 moyan Iori ninu ede filo re. Qlateju (1999: 278) jerii si eyi nigba ti 6 wi pe llo-ede je pna kan ti dhkpwe fi ri da onkawe laraya ati ona ti yoo fi mu k'i Ife-inu won fa si odd re. Gege bf a ti mo pe ede je okan la'ra awon nnkan ti awon onkawe ri gba'dun ninu Iwe kiko alatinuda, iru ede ti okdwe yoo Id yoo yatp si ede ojoojump, o' gbodp je eyi ti awon owe ati onsifrisii akanld ede ayawora'n dun gbdngbdn (Opaddtun 2003: 58). Ilesanml (1992: 106) so pe "ede ni atokun fun Ijoba, ede ni ogbufo fun esln, ede ni alore ofin ati 'itan, yala fi 'isenbaye tabi fi Igbadegba". 0 salaye slwaju sli pe "ede ni koriya ise, ede ni alarina gbogbo ayeye patapata porongodo. Abajo ti Ilesanmi fi w'i pe: Oso ara, psp ile, psp asp, psp aylka, gbogbo ohun to je Ibatan ewa pata, aroko la ri fi won pa fdmp adarihunrun; aroko si riiyi, ohun ni akpb! ede. Kd sdhun fi asa kan Ie se laifi tede se. (o.i. 106) Alaye Ilesanmi yii fi pataki ede han gege bl Ipite fun gbogbo eda adarihunrun. Adebajb (1992: 127) naa fi asopp atilbasepd fi 6 wa laafin ede ati asa han wa. 0 tenumd-on pe, "Ede la fi ri gbe asa ga. Bi a ba fe dekun asa Iran kan, ede la 6 kpkp gba lowo re". Ilesanmi naa gbe e lese: Ohun to kokp ri fi asa han ni ede. Bi awon eriiyan mute kan ile, bl won mule kan ile, bl ede won ba ti yatp si ara won, 6 di dandan kl lyate die wa ninu asa won bo ti wu kd ri. Ede Ie mu lyate asa gbddro gan-an. Niton pe ede ni liana Ibasepd to se pataki ju fun pmp eriiyan. 0 eya eriiyan meji kd ba gbd ede ara won, boya ni won fi le sowo pd. Mi opd 'igba ni awon oriisowo ri lo ede to yatp si ti ablnibt won nigba to ba je pe ede yii ni awon mejeeji gbd, fi won si fi le dunaadura ohun fi won jo gbe sori ate. Ede ni owo ri Id. (o.i 106) Way1 o, gege bl a ti fi i ninu alaye Ilesanmi, onalbanisdro fi a ko le e diyele ni ede je. Ede je irin-ise ati ohun eld ti dhkpwe fi maa ri gbe 188 ero okan re jade fun awon onkawe re. Ede ni irin-ise Ibanisprp ti mutu- muwa h Id lati ni Ibasepd ati Igbpra-eni ye. Mpase ede, ohkowe h kp awon onkawe nipa asa, 'isese, eyl ti yod ran awujo wa Ipwp. Bi ede ohkowe ti wuyi to, bee naa ni ohfa kan glriki yoo maa fa okan awon olugbo tabi onkawe sodo re, "Se ede to wuyi, nTi satokun fero". Bayii gan-an ni ti agba ohkowe, Aklnwunrrii Isola ri. Ojogbon yii je dgbohtafigl ohkowe ninu ewi, 'itan aroso ati ti ere onlse. bfinu ise yii, a 6 se agbeyewo tipri t1 a Id fun ayewo ati Itupale Iwe Itan aroso O Le Xt/yn. A 6 wo die lara awon pna-ede ti 6 sodo sinu Iwe yii. Ti^ri ti a fi se atupale Tipri ti a se amulo fun itupale ise y(i ni tipri Girama-eleto (Systemic Functional Linguistics). Agbateru tiofi yii'ni J.R. Firth, dun ni eni ti 6 kdko se awarilmo yii. 0 sise Iori ede, aworan atiltump. Ayeleru (2001: 35) so pe Firth fa Imo yii le akekoo re, Halliday, Ipwo, eni ti 6 tun tiofi yYi se, fi 6 si mu ki 6 dara si i. Tiofi Girama-eleto yii ri ede gegeii i 'ihuwasl, eyi ti d ri sise fun awujo. Ise patak'i ti tiofi yii ri se ni w1wollo-ede bi o ti balsele kan mu ati 'idi ti o fi waye. Tiofi yii wulo pupppupp fun itupale litireso. Bi o tile je wi pelwdlo ede po Idrislirisii, sibesibe, won ti je dindin ku si meta gboogi. Halliday (1992: 112) pin awon'iwulo tabi Ise t1 ede ri se si meta gboogi. Ik1nn1 ni "ohun ti o wa ninu ede", ey1 to fi ede han gege bl ohun kan". 0 ri se agbeyewo llo-ede fun agbekale ero ati 'iriri oluso tabi ohkowe ninu awujo ti o wa. Mnu Iwulo yii ni a ti ri oluso tab! ohkowe n1bi ti o ti ri fi ede so g bog bo'iriri re fun olugbo tabi awon onkawe re. Gege bi Olateju (2008: 76) ti so, "ede gege bi ohun kan" ri so fun wa pe ede eriiyan ni ojuse tabi 'iwulo, a si le Id 6 fun ohun pupp rii awujo wa. Eyi tump si wi pe rilpase irin-ise ede yii, oluso tabi ohkowe le tu 'iwoye re tabi 'inn re fun araye gb6. Mnu ise yii, a ri I pe Isola tulwoye ati 'iriri re jade ninu'iwe Itan arosp re 0 Le Ku. Iio ede Isola ti a fe gbe yewo yii ri sise fun agbekale ero kan ni. Ojo (2005: 44) se afikun pe'iwulo ede yii duro fun arbjinle ohkowe bi o ti tu u jade ninu'ilo-ede re. Gege b1 a ti mp pe'iriri Id maa ri gun ohkowe, Ise'iriri ni'iwulo ede yii ri gbe jade, eyi fi o ^i ba ise yii mu Ippplppp. Eyi Id mu ki Sdmdye (1990: 17) so pe, lati le rii Pye ero ohkowe, eriiyan gbpdp ronu jinle kpja 'iyprisl tabTise-pna yen Ip si ibi fi Iran ohkowe ti hit jade wa. Iran ohkowe yii ni awon'isele aylka tab! ti awujo. 189 Iwuld keji ti tipri yii ri topinpin ni "ede nipa sise ohun kan". Eleyii ni Iio ede fdn "ajpsepd ati Ibasepo pelu awon elbmiran". Ohkowe ati onkawe jo ni ibasepo laaarin ara won. Ohkowe le fun onkawe ni ojuse, eleyii ni awon ojuse tabi 'iwuld ede bi i bibeere, didahun, fitako lati le hi 'ifikunlukun ati agbpye. Olateju (2008: 77) se atenump re wl pe iwuld yii 16 h mu ki Ibasepo le wa', ki 6 si fesemule laafin ohkowe, onkawe tabi awon omo awujo re. Gege bl Olabode ti so ninu Olateju (2008: 77) nipase ede ohkowe la fi le da dhkpwe mp. Eleyii ni a ri pe ni ojuse ajumose. Ojuse ati Iwuld keta ni "mimu ki 'iseweku wa ninu ise-pna dhkpwe." Iseweku ni bl 'ibasepo laafin 'ikojopb, Isopp ati 'itayo se se regi Si" (Adesuyan, 1998: 111). Iwuld keta yii tun ri fun eni ti d ri Io ede yii ni agbara lati le ko Iwe ti 6 ba as'ikb ati igba mu. Se asp Igba la a da fun 'igba. Ohun ti 6 sele ni pe Iwuld keta yii ri se afihan 'ibasepo ti 6 wa laafin awon gbolohun fi 6 wa ninu'iwe, bl won se se weku si. Adesuyan (1998) so pe Iseweku ni d ri je ki a mb boya ohkowe wlire tabi kd wlire. 0 salaye sli w1 pe: Iseweku maa ri fara han ninu ete'iwohun, b1i raimu, 'ifohungbohun, 'ifohundara, didpgba, 'ijora batarii, 'ihunabbl. (o.i. ill) Bi a ba se akiyesl fiofi yii, a 6 fi i pe 6 ba ise yii mu. Tipri yii fi bi ohkowe se ran ede nise lati ko awon onkawe re lekbo. Bakan naa, a si ri orisiirisii ajpsepd laaarin awon eda-'itan re. 0 si ran dhkpwe Ipwo lati gbe ise pna jade; eyi ti o je'itewpgba Iodo awon onkawe re. Halliday (1992: 113) tile se afikun pe'iwuld keta b le se ise kankan lai si awon meji tb ku riibe. Ldi si 'iwulb keta, paapaa awon 'iwuld meji to ku kb le wa si 'imuse. Eyi fi han pe'iwuib meteeta fara kp ara won. Ona-ede Gege bi Olateju (2001: 92) ti so, ohun meji pataki lb je gbogbo bhkpwe/onise-pna alafede-gbe-kale logon. Ohun meji naa ni ewa ati ise ti won fe fi ise pna won je fun awujo. Lati ipase ewa, awon onkawe daraya ise-pna won je fun awujo, awon eriiyan yob kp pgbpn tabi ekd nibe, awujo yoo si tipa bee dara sii. Orisiirisii ni awon pna-ede ti 6 sodo sinu 'iweItan arbsp O Le Ku. Ona ti ohkowe gba Io ede re jp ni loju pupp, eyi s' 190 mu ki 'iwe O Le Ku yii di akagbadun, ati akatunka fun awon onkawe re. A 6 se ayewd die lara awon bkan-b-jbkan ona-ede naa ni sokisoki. Oro-Ayalb Orb-ayalb, gege bi Ayeleru (2001: 150) se so ni awon wunren kookan ti a ya wo inu ede kan lati inu ede miiran. Ojo (2005: 88) fi oro-ayalo han gege bl ohun ti ri fi eriiyan han gege bl eni ti b gbp ede meji. Oyetade (1990: 44) se afbmb re wi pe eyikeyn ninu awon ede mejeeji fi eriiyan gbo yTi ni eriiyan ri Id ju, filo yTi si wa lowpldi ti a fi fe Id b, eyi ti d si da'leri al rii. Oyetade teslwaju pe eriiyan ri dagajia ninu'imp ti o ri Id deedee nipa lyprisi tabi abajade ain1 re. Ohun fi Oyetade so yii se afihan Isola gege bi elede meji, paapaa elede pupp. Isola jade, b rita, d kawe, d si je sorosdrd ninu ede Yoruba. Nipa filo oro-ayalo gege b1 ona-ede ninu 'iwe re, Isola tipa bee so ede Yoruba di gbigbooro si I. Gege b1 Yoruba ti w1 pe "Aso Igba la a da fun 'igba". "Igba lonigba a ka". Igba d si durb sbju kan, 6 ri y1 ni. Pupp riinu awon eda-'itan inu Iwe yii ni alakowe. "Kd si b1 a b se se ebblb kd ma rungbe. Irufe ede fi awon eda-Itan yii yob maa Id, gbpdo toka won gege b1i alakowe. Ninu Iwe yii, a ri i pe awon wuren kan fi a ya lati inu ede Gees’i ni won fi bp gbdldhun ede Yoruba ti won ri so. Salami (1982: 125) salaye pe oro-ayalo orisii meji lb wa. "Orb ayalb afetiya"' ati "Orb ayalo afojuya". O salaye siwaju sii pe pro aya'lb afetiya maa ri wa'ye bi won ti so p, bi orb ti a pe ni ede Geesi yen ti dun ni eti wa la d se ya a wp inu ede Yoruba. Orb aya'lb afojuya ni tire maa ri wa'ye nipase bi a ti ri i ni kikp siie ni ede Oyinbd. Adeleke (2000: 162) naa kin Salami leyin nigba ti o' so pe aya'lb orb wa'ye nipase ajpsepo Iona okbwb, esln,’iselu tabi ekp kikp. O salaye pe: Bi apeere, Iran Ypruba se asepb pelu awon Geesi, Hausa, La'ru'ba'wa, eyi ni kb si je ki d ya ni lenu pe a n se ala'baa'pade awon eyp pro ede Geesi, Hausa ati La'ru'ba'wa ninu ede Yoruba. Adeleke se afbmp re wi pe "isbro aini orb to' se regi pelu awon eyp orb ti a ri ninu ede miiran Id fa yiya irufe awon orb bee wp inu ede Yoruba" O salaye siwa'ju sii pe orb aya'lb afetiya ma'a ri wa'ye bi won ti so o, bi orb ri a pe ni ede Geesi yen ti dun ni eti wa la o' se ya a wo inu ede Yoruba'. Orb aya'lb afojuya ni tire ma'a ri wa'ye nipase bi a ti ri i ni kikp sile ni ede 191 Oylnbd, ni a o se ya a wo inu ede Yoruba. Ade'leke (2000: 165), so fun wa pe awon eto liana kan wa ti a gbodd tele ti a ba fe se amu'lo ord aya'lo ninu ede Yoruba. Awon nab ni: i. Korisdnantl kd gbodd pan bro aya'lo ii. Isupb konsonanfi kd gbodd han ninu drd aya'lo ti a ya wo inu ede Yoruba. iii. Iio Ird ohun se pataki Iori awon ord aya'lo ti a ya wo inu ede Yoruba. Ede olo'hun ni Yoruba je. iv. A gbddo fi kdnsona'hti'ati faweli jiird korisdnantl ati faweli ord aya'lo ti a gbe wo inu ede Yoruba, paa'paa pelu fpnnmu Yoruba ti o sunmo fo'ntimu inu bro aya'lo naa. Apeere I: Nigba ti Ajani ati Asake ri Io si gbongan Trenchard fun ariya oti, ohkowe se apeju'we aso ti Asake wb. Ohkowe ni: Asake naa wo buba leesi, o' si rd leesi pupa rusu'ru'su kan ba'yii, o' ta gele genge. (o.i. 1) Ninu apeere dke yii, "leesi" yii je Ord aya'lo afetiya. 'lace' ni ni ede Geesi. Bi won ti ri pe ord yii, ni ede Gee'sl, bi d si ti dun leti wa ni a se ya a wonu ede Yoruba. A fi faweli "e" jiird faweli "a" ti o' wa ninu "lace" ni ede Geest. Bakan naa, ni a tun fi ird faweli V jiird faweli "e" ti d wa ninu "lace" ni ede Geesi. Niton' pe ede Yoruba je ede oldhun, ki o si le dun da'rada'ra ni llblro ohun ti a fi sori leesi, eyi mu ki faweli "e'" je meji. Apeere II: Leyin ti Ajani ati Asake ti jo tan, Ajani ni ki awon gbafefe Io si dnalsale. Ohkowe salaye pe: Won fin dfe, won debi Ijdkod Emeriti kan ba’yii, won si jo'kdo. (i.o. 4) Ninu apeere dke yii, "simehti" je ord aya'ld afetiya. "Cement" ni ni ede Geesi. Bi o' ti dun ni eti wa ni a se ya a wo inu ede Yoruba. A fi ird faweli ”i" ni ede Yoruba jiird ird faweli "e" ni ede Geesi. Nitori pe korisdnantl kli pari ede Yoruba ni a se fi faweli V kun un leyin ti o fi di "simehti". A si fi ami ohun si i Iori. 192 Apeere HI: Nigba ti Dotun, afe'sdna Lola' wa ba Ajani ati Lola ninu yara Lola, Ajani Deere ibi ti Dotun ti ri sise, Dotun si dahun wi pe: Ue redid kan nile yi ni. (o.i. 30) Ninu apeere oke yii, "redid" je pro aya'lb afetiya "radio" ni ni ede Geesi Bi d ti dun leti wa ni a se ya a wo inu ede Yoruba. A fi ird fa'wefi "e'" ni ede Yoruba jiirb ird fa'wefi "a" ni ede Geesi, a si fi ami ohun si i Iori. Apeere IV: Onkbwe se apeju'we asp ti Ajani wp. 0 salaye pe: Asp ginrii yelo bayii nl Ajani wo lewu. (o.i. 1) Ninu apeere oke yii, orb ayalo afetiya ni orb mejeeji yii; "ginrii" ati "yelo". Bi d ti dun ni eti wa ni a se ya a wo inu ede Yoruba. Bi a ti ri ko "ginrii" yii ni ede Geesi ni "Guinea" lati ara "Guinea Brocade". Bi a ti ri ko "yelo" yii ni ede Gee'sl ni"yellow". Ninu "ginrii" oke yii, a pa ird fa'wefi "u" ni ede Geesi je, d ku ird fa'weli "i" ni ede Gees), a si fi ami oke si i Idri, o' di ”i". A wa fi ird fa'wefi "I" jiird fa'wefi mejeeji "ea" ni ede Geesi Ni ti orb aya'lb "ye'lo", a fi iro fa'wefi "e" jiird fa'weli "e" ni ede Geesi, a s! pa ird kp'risdnanti "I" kan je nitori pe kl i si Isupb kdrisdna'htl ninu ede Yoruba. Ba'kan naa ni a pa korfsdnantl "w" je, d wa fun wa ni "yelo", a si fi ami ohun si i ti o' fi fun wa ni "ye'lo. Afiwe-taara Gege bi Adebbwale (1998: 144) se so, awon bnkbwe maa ri sa ipa won lati ri i pe awon onkawe ri fi oju-inu ba awon Isele inu Itan Ip. 0 safihan pe ona ti won saaba maa ri gba se eyi ni filo afiwe-taara ati afiwe-elelbp. Oatunfi (1984: 53) se afihan afiwe-taara gege bi ohun tu maa sapejuwe ohun kan gege bl ohun to dabi ohun miiran. 0 rii rii ile Yoruba, a maa ri se afihan afiwe-taara pelu wunren "bl". Opefeyitlm'i (1997) salaye pe afiwe taara maa n waye nigba ti a ba fi nhkan meji we ara won, a 6 si fi am. afiwe-taara bit "bi", "dabi" ti b fi won we ara won. Ajiboye (2002: 71) ■ 2a se afiku'n pe afiwe-taara ma'a ri ni awon koko meji ti wp'n du'rd ni igun ■ obkan. Awon ko'kd meji yii gbpdb ni orita ti won ti pade', eyi ni ohun gan an ti d pa wp'n pb. Apeere pb jantirere rimulwe OLeKw. 193 Apeere I: Nigba ti Ajani ati awon ore re wa ni ibi ariya, olu'kuluku Io jo pelu awe pmpge won. Nigba ti won ti jo, ti d Si ti re won, won here si pada wa Ijokod won. Ohkowe wa salaye pe: Gbogbo won h sare mu oti, bl eni to sese toko osan de. (o.i 2) Ohkowe fi bl won se h sare mufi we ti eni t'i d sese toko osan de, oungbe ti gbe daradara nitori pe la'siko dorun, ara ma'a ri gbe, o' si ni dpolopo omi. Ajani ati awon ore e re ti jd jd jd, d si ti re won, won nild la fi oti sa'ra. Ohkowe ri ya aworan eni ti oungbe ti gbe spkan awon orikaw re. Orikowe fe ki awon onkawe dun ma'a fi oju'-inu ba awon Isele inu Ita naa Ip. Apeere II: Nigba ti Ajani ati Asake tun fa ara won lowo Ig si ibi ijo, orikowe sala^ pe: Efi won ti pada Io ni won tun ri ri awon eriiyan fi won duro si kbrp ni mejimeji, fi won ri kun hunnu- hiinnu bl ologbo fi ri jeran. (o.i. 6) Orikowe ri fuses! awon meji fi won ri mufee yii we'isesi ologbo ti ri jerai Si ologbo ba ri jeran lowo, yoo maa kun, niton pe eran ni ounje ologb Bi o ba se dun md awon ololufe meji yii to ni won ydd se maa kun. Wc ydd maa fenu kora won lenu, fpwd pa ara won lara, won yoo si m< gbadun ara won. Apeere III: Ajani so fun Ijaola pe dun fe tete gbe Asake nilyawd, ati pe ord naa ri I dun lorninu. Ijaola wa kg g pe nise ni kd fa oju Asake mpra, ki o' tan t titi ti gwd yod fi ba a. Ijaola wa pa owe yii lati fi we pg bon ti Ajani maa mu Asake. 0 wa' so gbo'ldhun yii: Ba a jelubp bj elubp la a ri, Eni to fe mdbo, ydd se bi bbo. (o.i. 14) Owe Yoruba riiyi, sugbdn afiwe-taara jeyo riibe, wunren "bi" ni o' si Orikowe fi' eni ti d fe jelubp we elubp nitori pe, bl 6 ba Ip elubp yii lei elubp a gbon si i lara, bl d ba si fe e jd 6, elubp a kun gbogbo irun, ara 194 asp re. 0 ti di elubo riiyen. Bakan naa, ohkowe se afiwe eni to fe mpbp, ti 6 dabi dbp. Obo maa ri hiiwa b'i ode, eni fi 6 fe mu un naa gbodb huwa bl ode. Iforifi ati Ipamora titi ti owp eriiyan yod fi ba oun ti o n wa' ni eyi kd wa. Apeere IV: Akdko'idanwo ni ogba Yunifasifi ki i se akokd ti o' rerun, ki i se akokd ere rara. Idi eyi ni pe, ko si eni ti o' fe fidi remi. Bi a ti ri agbalagba akekop, bee naa ni a ri ompde ake'koo nibe. Ohkowe wa ya aworan-inu ohun ti o' ma'a ri sele ni asiko naa. O salaye pe; Tomode-tagba a ru hangogo bi aja ole. (o.i. 22). hiinu apeere oke yii, ohkowe se afiwe bi tomode-tagba se maa ri ru lasiko Idanwo nitori aisun, aijeun ati aisinmi daradara we bi aja pie se maa ri ru. Aja ole maa ri ru nitori pe ko fi Itoju, ounje ati awon oogun to ri se ara loore. Ole b fi 1 toju ara, re tan, k'i 6 to rant! ati toju aja kan. Iru aja bayii I6 maa ri bunije, a si ma a kanra. Aspregee Ona-ede yii ni a tun le pe rii ampga tabi aspjaamu. Aspregee ni ohun tabi 'isele fi ko sele tabi waye. Eyi ni pipon nhkan ju bi 6 ti ye Ip, tabi siso nhkan di ona llopp-ilppo ki iyi re ba a mu onkawe tabi awujo Idkan. Olatunji (1984: 55) fi aspregee han gege bi ohun tabi eriiyan fi a sorb re tabi gbe ga ju bi 6 ti je Ip. Inu ewi alohun ni eyi ti wppd. Babalola (1976: 75) pe e ni "abump", 'Ibukun pro", eleyit si maa ri sele ninu Ijala are' ode, o si ma'a ri sise Ipanilefin-in. Azarida (2007: 36) salaye pe filo aspregee ni k1 a se apejuwe tabi rdyin ekunrere, eleyit si maa ri ya aworan ohun naa, sinu okan olugbo, eyi yod si je k1 6 tubp ye e s1 i. Fajenyp ninu Azarida (2007: 36) pe e ni "m1mp nhkan rii ampga. Ona-ede yii maa ri mu ise ona dun ni, kii je ki 6 tete su eriiyan. Apeere I: Leyin ti Ajani ti pari'igo sitabtu kan tan nibi ariya ti dun ati Asake Ip, pti yii wa ri sise to gbogbo isan ati orikeerikee ara re. Ohkowe wa' se alaye pe: ...on re wa pe b! or'i aidjp Somdlii to fpdun meta gbajp Ipwp egberun eriiyan lai kprukp eriikankan site bee ni ko si si wo san feriikankan. (o.i. 1). 195 Asoregee ni gbo'ldhun dke yii. Ko se e se ki alajo Spmblu fpdun meta gbajp lowo egberun eriiyan, lai ko prukp eriikankan s'ile, ti kd s'i si owe san feriikankan. Eleyii kd se e se, kb Si le sele. Amoga orb ni, o si ri sise 'ipanilerin-in ati Ipon orb le ki orb tabi ise pna ma ba a je sa'kala. Apeere II: Nibi agbo ijd, Ajani ni Ri Asake je ki awon jo nase bo sita, ki awon si gbafe'fe Io si ona 'isale. Nibi ti won ti ri nase Ip ni won ti ri awon meji ti wp'n sun kale. Asake wa beere pe, kin ni won ri se? Ajani ni won ri miifee ni o. Asake wa beere pe ti ejb ba wa bu wp'n je ri kp? Ajani wa da'a Idhun pe: Ejb paapaa maa ri bbwb fawpn to ba "ri mufee" (o.i. 5). Asoregee ni gbo'ldhun yii. Ejo kb mp eriikan seriikan, k'ii si i se eriiyan ti yoo fi bu u san bbwb fun eriiyan. Eni ba kpja aaye re, ejb a busan an. Ise ti asoregee ri se ni pe d ri mu ise pna dun ni, 6 si ri panilefin-in. Kii je ki 'iwe' su eriiyan. Ise appnle orb Id ri se, k'ii je ki ise pna gbe funJ. Apeere III Ninu arbfb 'ife ti Ajani kp fun Lola, apejuwe ati appnle ti d se fun un fa kikL Ajani wi pe: Oju bii tarigefi. (o.i. 40) Asoregee ati abump ni gbo'ldhun dke yii. Ajani se apejuwe bi oju Lola se jp ti arigeh. Ajani ti kb ri arige'ti ri de bi pe yob ri oju re, fi oju Lola we ti arigeli. Ohun ti Ajani salaye re ni pe oju Lola' wuyi, d Si fanimpra Ippblppb. Ise ti llb-ede yii ri se ni lati pa awon onkawe lerin-in ati lati fun awon onkawe nnmbla'ra. Apeere IV: Ni ibi aisun 'igbe'yawd pre Fu'nmi, nitbsi bdb awon Ajani la'pa' btu'n ni awon egbe egbp'n pkp 'iyawd jokbd si. Ohkowe se apejuwe iye awon ob'inrin ti wp'n kd tira. 0 wi pe: Won kd oblnrin tira bi egberun. (o.i 61) Asoregee ni gbdlohun bke yii. Ba'wo ni ob'inrin bi egberun se le jdkbd si apa btu'n awon Ajani? Ob'inrin melbo gan-an Id wa nibe lapapb? Ele'yi* kb le sefe! Ohkowe se eleyii kilwe re ba a je akagba'dun ni. 196 Apeere V: Nigba ti Ajani ri fi foto okan ninu awon ore ob'inrin ti d ti ni ri han Ijaola, d sapejuwe okan ninu won ti o' je omo oga re bayii: ... sugbdnIgbagbo' re pd ju tawon omo eyin Io (o.i. 18) Ninu apeere oke yii, Ajani se afihan ‘igbagbo omo oga re gege bi eyi ti d ju ti awon omo-eyin Ip. Awon omo-eyin Jesu Id ri tpka si; eleyii ko Si se e se. Asoregee ni, d si ti kpja' bi pro se ri gan-an. Nigba ti awon onkawe' ba si ri kaajmplara yoo je jade. tfohunperiiyan Ona ede yii ni a ri lb nigba ti a ba fun ohun ti kb lemii, tabi ohun ti a kb foju ri ati awon ohun miiran ti kii se eriiyan ni agba'ra lati huwa bi eriiyan. Ifohunperiiyan ni gbigbe'isesi ati'irisi eriiyan wp nhkan tabi ohun ti Kii se eriiyan. Bi orb se ka ohkowe la'ra si Id si fa eyi. Ifohunperiiyan ri je ki ise ona dun, ki d mumu laya eriiyan. Bakan naa Id si tun ri je ki Orb kurb ni orb saka'la'. ApeereIfohunperiiyan sodo si inu Witan arosp OLeKu. Apeere I: Nigba ti Ajani ri se apejuwe Asake ninu arbfb 'ife ti o' kp fun un. Ajani wi pe: Oju meji ti dundu'n ni Ohun kan ni i fi i fb. (o.i. 21) Ninu apeere bke yii, ohkowe gbelsesi ati Irisi eriiyan wp 'ilu dundu'n bi d se loju meji, ti d tun ri fphun bi eriiyan. Ohkowe Io Ilu dundu'n gege bi eriiyan kan ti d loju meji, ti o' si ri fohun bi eriiyan. Eleyii ri ft han bi awon ohkowe se ri Io ohun al^ilernii gege bi eriiyan lati mu' ki ise pna won joju loju awon onkawe. Apeere II: Ninu arbfb'ife kan naa ti Ajani kp fun Asake, Ohkowe wi pe: Bi bata ba ri rajb Ki saworo eti e kd ma'a telee (o.i. 21) Ninu apeere bke yii, 'isesi, abuda ati Irisi eriiyan ni bnkbwe gbe wp llu bata, bi d se ri rin 'irin-ajo. Bi d se la'gba'ra bi eriiyan, lati re ajb fu'nra re, ati bi saworo eti e yoo se ma'a tele e. Eyi tump si i pe saworo eti e naa 197 lese lati tele'ilu bata. Ise'ipanilerin-in ati'ibuyi kun ord ni'ilb-ede yii ri se nibi. Ajani fe kl'imblara Asake ga soke ni, ki'ife Ajani si kun inti okan re, pe bi Asake ba ti ri lo ni ohun naa yoo maa tele e. Apeere III: Ninu arbfblfe ti Ajani kp fun Lola, 0 wi pe: Labalaba ba le ododo', Ododd ri binu. (o.i. 41) Ninu apeere oke yii, 'ifohunperiiyan ni "ododd ri binu". Isesi ati 'ihuwas eriiyan ni dhkowe gbe wp ododd. Eriiyan ni maa ri binu. Eriiyan ni i ft ere okan atnmolara re han. Ododd wa ri huwa bi eriiyan. Eyi mii ki ise ona y i wuyi pupopupo. Ilb Owe Ord pgbpn ni owe je. Owe Id duro gege bl epo ti a fi ri je isu orb, ti Itumt re'i ba runi Idju b1 egbe isu fi ri fun ni Iprun. Olatunji (1984: 169) nae salaye pe awon Yoruba mp rifi owe gidigidi, nitori pe won je pgbpr atayebaye. O salaye slwaju pe owe jelsese tabi abalaye, enu agba si lob ti i gbo. Azanda (2007: 60) fi owe han gege b1 i gbdlohun to ri fi pgbpr ati Imoglnie Yoruba han. 0 salaye pe owe naa ni kpkpro t1 Yoruba fi 1 s 'ilekun bro, bl eriiyan ba se gbp ede Si ni 6 se maa mp owe 1 lb to Bamgbose (1974: 120) salaye pe nigba ti ohun kan tabi Isele kan ba le n a nilb owe lati yanju 'isele naa. Bamgbose tenump on pe ohkowe le k( bkifi owe le owe loju kan naa, nibi ti owe kan b ba Id koju ise t1 a fe ko je. Ojo (2005: 147) tile so w1 pe a le tun owe pa Iona t1 kb fi rii be owe je, ey1 ni atinuda ohkowe. Isola, gege bl a ti mb, loyun orb, emu me si ri ta ni ikun re. Owe tire k'ii se asadanu. Awon owe kahka wonyi mu k 'iwe O Le Ku jade s1 gbangba, d si se e na si awujp. Ona ti Ojbgbpn y gba lo owe je ohun ti o' wu'ni Iori lo'pblppb. O lo asinpb owe lati salay* 'isele kan. Idi ni pe owe kan soso b le koju ise ti brikpwe fe ki d je ni ibi: o ba ti lo asinpb owe. Iio asinpb owe yii fi bi orb yii se ka brikpwe lara to ti d Si fe ki o' ka awon onkawe re naa lara. Bakan naa ni ohkowe tun s ayipada owe, o' si tun lo awon wu'nren kan mo owe. 198 a. Ild asinpo owe Apeere I: Isola fi ild asinpo owe si enu ijaola, nigba ti pro baba Asake su Ajani, ti kd mo ohun ti d le se mo, Ijaola ko o ni ohun ti yoo se. 0 Io owe merin lati fi gbelmbran re kale: A! gbp, a k'i i gbdn bi eni ti ri tan ni. Eni ti a b baa ta, bibb la a kp bo o. Baa jelubp, bi elubp la a ri. Eni to fe mobo yoo se bi obo. (o.i. 14) Itumb kan naa ni awon owe mereerin yii fun wa. Eyi ni d si fa a ti ohkowe yii fi sin won papp lati salaye Isele kan soso. Itumb naa ni pe eni ti a fe mu naa ni ki a kpju si, ki a si maa so p ki o' ma bp Ipwo wa. Ohun ti d ba si gba ni ki a fun un, ki a le ni ayprisi rere. Eyi ni pe ki Ajani Io pgbo'n, ki o' ma si je ki Asake fura titi ti yoo fi mu un, tabi fe e gege bi aya. Apeere II: Ohkowe tun Io asinpo owe nigba ti Ajani kp Lola pe ki d mase ba Dotun ja, sugbpn ki o' fpgbp'n ja a sile. Ajani wi pe: Aabd ord laa so fun pmplu'abi, to ba de'nu e, a dodidi. Aja to' ti ri ri ni to ri yoru, bo ba ri ni to ri gbo', a b ti mb pe nhkankan ri be ni. (i.o. 42) Ninu apeere bke yii, ohun ti Ajani ri tenu mp fun Lola ni wi pe'lwa re ni ki o' fi le Dotun ki o' ma fenu so o'. Nigba ti Dotun ba ti ri Iwa re ni yob ti ma'a ba ese re sorb diedie. Ise 'itenumo ki orb le ye ni ye'keyeke ni ise ti asinpo owe ri se. b. Sise ayipada owe. Apeere I: Leyin ti Asake ti lo'yu'n fun Ajani, ti Lola si wa lati ki Ajani, Ajani bere si se tlkbtikb si Lola', ohkowe wa ja owe yii si i: Awo tee're bonu, egberun erb ri be ni 'saleldodo. (o.i. 73) Ninu apeere bke yii, bi a se ri pa owe yii ni, "Awo fele bonu, kb je a riku'n asebi". Sugbpn bnkbwe Io atinu'da lati se lyipada owe yii, eyi kb si ba 199 aawe je. Nise ni o tubb ye ni yeke'ye'ke. Itumo owe yii ni pe Ajani ri dibdn fun Lola ni, Lola d st le ri ohun ti o' ri be ni ikun re. Apeere II: Nigba ti Ajani ati Asake lo ki ore baba re, baba Ajasa, 0 so fun won pe baba aladuura ti won lo ba yoo se ohun tf baba Asake fe ni, d wi pe: Aa, ta lesul ba gbe bi ko se agbe'bo? (i.o. 88) Bi Yoruba se ri pa owe yii ni pe,' Tani esinsin 1 ba gbe bi kd se ele'gbd? Itumo re ni pe ti baba kekere ni Ke'leebu ala'duu'ra maa se nitori pe dun Id gbe' ise fun un. Yoruba s'i ni eni ran ni nise laa' beru, a ki i beru eni ti a a je fun. Ohkowe fi esu ropo esinsin, d Si fi agbebo rdpd elegbo. Ise ti o' ran ede naa ni ede je. Ifbrbgbebrb ni ohkowe se. Nibi ti a ba' ti ri esu, agbebo ni a o' ma'a reti. Nigba ti a ba' s'i ri elegbo, esinsin ni d kan. Ohkowe lo awon wu'nren kan mo dwe ti d Id. 0 fi won se ayimord. Bi apeere: Sugbo'n ayangbe aja dun, ki la d je kaja o' to' gbe? (o.i. 18) Se akeregbe ni yoo so'bi ti a ti maa tokun bo ohun (o.i. 28) Sibesibe, a le gbo kiku bjb la'sa'n, ka dami agbada nu (o.i. 43) Bee, a Rii le'ku meji ka'ma pbfo (o.i. 43) Bi a ba s'i ri pe Iori imi, a le rabuke eesin (o.i. 50) Won ni o su Ipja o d nu di, eriiyan melbd lo ma'a fedi han. Ohkowe tiin lo orisiirisii dwe bi dwe Igbeyawb, dwe Ibaldpd, dwe Oju-ojp, dwe ofin, owe esin, dwe 'itan abbl. Bakan naa ni o lo dwe eya- ara, ninu eyi la ti ri dwe'idi, dwe ori, owe pwo, dwe ese, dwe eyin abbl. Ninu 0 Le Ku, orisiirisii owe ni drikqwe mulb, eyi ti 6 fi han gege bii "pmo- odo agba". Itumo orisii meji ni owe maa h fun wa. Itumo erefee ati 'itumo 'ijinle. Apeere I: Eyi je dwe Ibaldpd Ajani fe tu asp tf Asake rd nigba ti won nase bo sita. Sugbdn Asake kb gba fun un, d wi pe: Ohun ta a ba maa je sun a kli ji i je. (o.i. 5). 200 Itumb erefee ti apeere oke yii fun wa ni pe, awa la ni ounje yii, ko to k'i a tun Ip maa ji i je. 0 ye k'i a bo sidii re pelu'igboya, k1 a si je e bl a ba fe je e. Itumo'ijinle ni pe suuru se pataki, akoko ni ohun gbogbo wa fun. Asake ati Ajani yoo ni aaye pupo lojo 'iwaju lati sun pd ati lati se ere Ife ti 6 ba wu won lati se. Si won ba h se e bayfi, won kd le gbadun re to bi Igba ti won ti de aaye won. Apeere II: Eyi je Owe Ofin Nigba ti Ajani ati Dotun, afespna Lola pade ni ile-iwbsan, won kd ki ara won nitori pe won ri ja si ord ob'inrin. Ohkowe salaye pe: A ki i ti ile ejd bo ka' sore. (o.i 76) Itumb erefee ni pe, kb si bi eriiyan meji se le re mo la'ilai, ti won ba ti ja, ti won si ti kd ara won de kobtu. Itumbljinle ni pejja b da'ra. O ye ki a sa fun ohun ti d le kd eriiyan sita bi omo pjp mejo. Kd si bi ajpsepd se le dan mp'ran bi Ija repete ba ti wa laarin ore meji. Apeere III: Eyi je owe Oju-pjd Nigba ti Asake se Ajani, ti Ajani si pinnu lati fi lya je e, Ajani wa pinnu pe, bun yob Ip wb d ki bun to mo iru'iya to ye e. 0 pa owe pe: Wiwe la a we ka to jare oye. (o.i 16). Itumb erefee ni pe b1 6 tile je pe aslkb oye kii se Igba ti eriiyan maa n nifee si lati we, sugbpn bl eriiyan ba ti le we, eriiyan ti segun pye, 6 si ti bori pye riiyen . Eriiyan ti jare, 6 si ti yeye oye. Itumo Ijinle ni pe a rii lati sapa lati se awon nhkan ti 6 ye lasikb, nigba t1 6 rerun ati 'igba ti kb rerun. O ko wa lati rii'ipampra ati'ise-ara-eni. Nitori pe, eni fi kb ba le se ara re kb rii le bori Isbro. Ajani pinnu pe bun kb rii da sefia fun Asake, afi 'igba ti bun ba Io mp'idi ti 6 fi hu iru'iwa yen si bun. Lllp lati beere yen Id fi bori Isbro yen. Apeere IV: Eyi je Owe Isirb Ni ibi yii, Lola ja Dotun sile, d si bere si tele Ajani, Dotun wa kp leta burdku si Lola. Nigba ti Lola fi leta yii han Ajani, Ajani wa kg Lola pe, diedie ni ki d maa fi han Dotun pe orb won kb le wb mp, Ajani wi pe: Aabb brb la a so fomoluabl bo ba denu e, a dodidi. (o.i 42). 201 Itumo erefee ni pe omoluabl ti ni aabb ord ti 6 ti wa nlkun re tele. Oro tete maa ri ye Omoluabl. Omoluabl ni omp atata, ti 6 gbeko ti dye ord maa n tete ye, eni fi 6 ti ile rare jade wa. Nigba t1 a ba tun wa so aabd ord fun un, a wa di odindi ninu re. Isirb yii ni'idaji pelu Idaji, a di odidi. Idaji pelu'idaji -* odidi 1/2 + 1/2 = 1. Itumo Ijinle ni pe Yoruba ki i fi gbogbo enu sorb, nise ni won maa h pe ord so. Nipa bayTi, plpgbbn omo yoo ti rii bye bun ti a pe so. Way! 0, ohkowe O Le Ku fe ki a mb pe kb s1 Isele tabi ipb ti awon Yoruba kb rii owe fun. Awon owe wbny! fi asa Yoruba han wa. Won si duro gege bi ofin tabi liana ti awon Yoruba ri tele laibeereldi ti 6 fi ri bee. Agbalogbabb Ise yft je ki a mb pe ise ona kan kb le je'itewbgba Iais1 ede tabi ona-ede to yanrannb. A gb’iyanju lati fi han pe bnkbwe 0 Le Ku gbo ede Yoruba, 6 si fi aaye patak'i sile fun ona-ede ninu agbekale re. 0 lo awon erbja ona- ede oldkan-b-jbkan, eyi ti 6 mu k1 ise re rewa, ki 6 si dun un ka. Awon ona-ede ati erbja abalaye re duro gege b1 iyb inu obe, eyi si mu un tayo. Eli 6 se lo ede ninu'iwe Itan aroso re wuni Iori pupb. 0 han ninu apileko yii pe tiofi Girama-eleto la ti fi se atupale'iwe yii. Ise patak'i ti tiofi yii se ni w'iwo ilb-ede b1 6 ti ba 1di ati Isele yen mu. A ri i pe ede dur6 gege bi ojuse lati fi so'iriri ati'iwbye, eyi ti a fi riinu ise Isola. Iriri yn 16 s1 gun un ti 6 gun un n1 kese lati kolwe yii. Ise yii tun toka s1 'ibasepo ati ajosepb ti 6 wa laarin brikpwe ati onkawe. Laise-ariianl, 6 han gbangba pe Akinwumi Isola je ohkowe alatinuda, ti 6 mo riri ild ede bi 6 ti to ati bi d ti ye. Iwe Itokasi Adebajb, S. (1992). Awon Asaaju Ohkowe Yoruba Lati Odun 1848 Titi Di Odun 1930. IF. Odunjp Memorial Lecture Series No. 3. New Findings in Yoruba Studies. Ed. Akin Isola. Ibadan: Johnmof Printers. Adebowale O. (1998). "Ilb-Fde Ninu Itan-Arbso Akinlade". Journal of Nigerian Languages. Vol. 1 No. 1, pp. 141 - 157. Adeleke, D. (2000). "Eke? Itumo Ede Yoruba'." Eko Ede Yoruba Fun He'-Eko Olukgni Agba. Abeokuta: Visual Resources Publishers. 202 Adesuyan, A. (1998). Ifoju-Imo-Eda-Ede Ajemp-Afp wo Atoto-Arere: Ak'iyes'i Mofoloji. Zo-Bia-Wa. Jouma! of Nigerian Languages. Vol. 1 No. 1, Pgs. 107-114. Adeyinka, Yemi (2000). "Eka Ede Yoruba'.'' Ninu Olatunji Opadptun (olootu) Eko Ede Yoruba Fun Ue-Ekb Olukoni Agba. Abeokuta: Visual Resource Publishers. Ajiboye O. (2002). Litireso Yoruba (Ifaara). Ilorin: Ema Books. Ayeleru, Babatunde (2001). "Sony Labou Tansi's Literary Idiolect in La Vie et Demie and L'Etat Honteux." Ph.D Thesis. University of Ibadan. Azanda, O. (2007). Ilo-ede Ninu Orin Emi ti Ajlh'inrere Niyi Adedokun ati Ojo Ade Ko. Ise Akanse ti 'iwe Asekagba fun Oye Keji EM, EE (M.A.) Eka Imo Ede Litireso, Asa ati Ona Ibanisoro. Yunifas'iti Ipinle Eko (LASU). Babalpla, Ajiboye (1976). The Content and Form of Yoruba Ija/a. Ibadan: Oxford University Press. Bamgbose, A. (1974). The Novels of D.O. Fagunwa. Benin City: Ethiope Publishing Corporation. Fajenyo, S. (2000). "Iio-Ede Yoruba, "Ekd-Ede Yoruba fun He-eko Olukoni Agba. Abeokuta: Visual Resources Publishers. Fatdkun, E.O. (2000). Studies in English Language. Ibadan: Enicrownfit Publishers. Halliday, M.A.K. (1992). Language as Social Semiotic. The Social Interpretation of Language and Meaning. London: Edward Arnold. Ilesanmi, Makanjupla (1992). "Ipo ati Ipa Litireso Ninu Asa Iblle Yoruba." in Akinwumi Isola. New Findings in Yoruba Studies. J.F. Odunjo Memorial Lecture Series No. 3. Ibadan. Isola, Akinwumi (1978). "The Writers Art in the Modern Yoruba Novels" Ph. D, Thesis University of Ibadan, U.I. Isola, Akinwumi (1974). OLeKu. Ibadan: University Press Plc. Ogunsina Bisi (2009). Language, Literature and the Development of Education in Nigeria. Mocped Jouma! of Languages and Literatures. Vol. 2: No. 1. Ojo, Titilayp (2005). The Literary Idiolect of Kola Aklnlade's Yoruba Detective Novels. M.Phil Dissertation, University of Ibadan, Ibadan. Olabimtan, Afplabi (1986). "Ild lyapa bi Ona-ede ninu ewl Apileko". Laangbasa. University of Lagos, No. 3. o.i. 77 - 86. 203 Olateju Adesola (1999), The Language of Yoruba Drama: Adebayo Faieti's Basorun Gaa. As A Case Study. E. Ifie (ed). Essays in Honour of Prof. Adelugba at 60th Ibadan: End-time Publishing House, Pp. 277-293. Olateju Adesola. (2001). "Imo Isowo'-lo-ede Apa keji." Akojopo Imo Ijinle Yoruba. Oyo: Andrian Publication Series. Olateju Adesola (2004). "Readings in Advanced Yoruba Stylistics." University of Ibadan. (A Monograph). Olateju Adesola (2008). Stylistic Humor in the Drama of Akinwumi Isola. Emerging Perspectives on Aklnwunm'i Isola. Ed. Aklntunde Aklnyem'i and Toyin Falola. Trenton: Africa World Press Inc. Olatunji, O. (1984). Features of Yoruba Oral Poetry. Ibadan: University Press Limited. Opadotun T. (2003). Ohkowe ati Iwe-kiko Aiatinuda. Oyo Odumatt Press Publishers. Opefeyffimi, Ayo (1997). Tiofi ati Isowoloede. Osogbo: Tanlmehln-Ola Press. Oyetade, Oluwole (1990). "Nupe/Yoruba Endoglossic Bilingualism in Saare/Tsaragi in Kwara State". Ph.D Thesis, University of Ibadan. Salami, A. (1982). "Vowel and Consonant Harmony and Vowel Restriction in Assimilated English Loan Words in Yoruba'." Yoruba Language and Literature. Ibadan: University Press Limited. Somoye, Titilayo (1990). "The Thematic Analysis of Yemfitan's Gbobanlyi and Aklnlade's Sahgba Fo: The Hermeneutics Approach". M.A. Project, University of Ibadan. 204